Ọwọ́ tí ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá gbé, ara rẹ̀ ló fi ń nà o.
ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ TI BÁ WA GBA ÌJẸ́-ORÍLẸ̀-ÈDÈ WA PADÀ, NÍ OGÚNJỌ́ OṢÙ BÉLÚ, ẸGBÀÁ ỌDÚN Ó LÉ MÉJÌ-LÉ-L’OGÚN
ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ TI BÁ WA GBA ÌṢÈJỌBA-ARA-WA PADÀ NÍ ỌJỌ́ KÉJÌLÁ, OṢÙ IGBE, ẸGBÀÁ ỌDÚN Ó LÉ MẸ́RIN-LÉ-L’OGÚN
ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÚBÁ TI JÁ’DE KÚRÒ L’ARA NÀÌJÍRÍÀ, KÌÍ ṢE ARA NÀÌJÍRÍÀ MỌ́.
ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ JẸ́ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA AṢÈJỌBA-ARA-ẸNI
ÒUN NI ORÍLẸ̀-ÈDÈ TUNTUN JÙLỌ NÍ ÀGBÁYÉ !
GBOGBO Ẹ̀YIN TÍ Ẹ NṢE ÌFẸ̀HÓNÚ-HÀN NÀÌJÍRÍÀ NÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ, ÀJÈJÌ NI Ẹ JẸ́ L’ORÍ ILẸ̀ WA; ÀWỌN GÓMÌNÀ YÍN NÍ YÍÒ JẸ́JỌ́ Ẹ̀SÙN Ọ̀RÀN TÍ Ẹ NDÁ YÍ