Bí àwọn ọmọ Íbò fẹ́, bí wọ́n kọ̀, ohun tí òfin ìjọba Democratic Republic of the Yoruba (DRY)  bá ti sọ ni wọ́n máa tẹ̀ lé. 

Ó dà bíi pé, kò tíì yé àwọn ọ̀mùgọ̀ ọmọ Íbò yí bó ṣe nlọ, wọ́n ṣì rò pé Nàìjíríà la wà. Àánú wọn kò ṣe mí rárá; wọn kò mọ̀ wípé gbogbo ìwàkuwà tí wọ́n ti ń fi ẹnu wọn wà, láti ọjọ́ kéjìlá oṣù igbe ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rìnlélógún yí, ọ̀ràn ni wọ́n ń dá lábẹ́ òfin.

Àti àwọn, àti elòmíràn tí wọ́n nlò láti ṣiṣẹ́ fún wọn, ọ̀daràn ni wọ́n.

Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, Youngest country in the World 2024

Láìpẹ́ yí ni a tún rí òmùgọ̀ òyìnbó kan lórí ẹ̀rọ Ayélujára (á ò wá mọ iye tí àwọn Íbò san fun ò), tí ó ńfẹnu wa ìwàkuwà, tí ó nbú Yorùbá, tó tún nsọ pé Íbò ló máa ṣe àkóso Nàìjíríà!

Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá wa sọ fún àwọn òpè Íbò wọ̀nyí pé, a mọ̀ tẹ́lẹ̀ pé ọ̀mùgọ̀ paraku ni wọ́n; ṣùgbọ́n kí wọ́n ní sùúrù díẹ̀, nítorí pé a ò bá wọn jà sí Nàìjíríà rárá; ohun tí ó bá wu Íbò, kí wọ́n máa ṣe ní Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ní ilẹ̀ Yorubá ó, àwọn ọmọ Íbò ti tẹ́ !