Tinubú Tún Ti Kọjá Àyè Rẹ̀ O! Ó Gbé Orúkọ Wọlé Ṣóyínká Lé Orí Gbọ̀ngàn Ìtàgé Ní Surùlérè!

Tinubú Tún Ti Kọjá Àyè Rẹ̀ O! Ó Gbé Orúkọ Wọlé Ṣóyínká Lé Orí Gbọ̀ngàn Ìtàgé Ní Surùlérè!

Ṣé wọ́n ní ajá tó máa sọnù, kò ní gbọ́ fèrè ọdẹ – òun ni ọ̀rọ̀ Tinubú, ààrẹ wọn ní ìlú tó fẹ̀gbẹ́ tì wá, nàìjíríà, tí wọ́n nfi ipá dúró lórí ilẹ̀ wa báyi, tí ó yí orúkọ Gbọ̀ngàn Ìtàgé ní Surulere, ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, sí Gbọ̀ngàn Àṣà àti...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

  Báwo ni ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ṣe wá kàn wá báyi o? Kò kàn wá, rárá, ṣùgbọ́n kí á lè fi mọ̀ ọgbọ́n àrékérekè tí àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun máa nlò láti jẹ gàba lé orí ènìyán dúdú! Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Nigeria Nwá Oríṣiríṣi Ọ̀nà Láti Fa Ọmọ Yorùbá Mọ́ra!

Óríṣiríṣi ọ̀nà, báyi, ni Ìjọba àwọn ìlú agbésùnmọ̀mí tí ó fẹ̀gbẹ́ tì wá, èyíinì, Nàìjíríà, nwá báyi o, láti fa ọmọ Yorùbá mọ́’ra, àti láti gbé ojú wọn kúrò ní Orìlẹ̀-Èdè Yorùbá!   Èyí tí ó tún jẹ́ ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ sọ báyi, wípé, àwọn ilé-iṣẹ́...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Bí Àwọn Fúlàní Agbébọn Ṣe Gba Ìlú Ọ̀yọ́ Ilé

  Arákùnrin kan ni ó fi fọ́nrán kan sórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí ó ti sàfihàn bàbá àgbà kan tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìlú Ọ̀yọ́ Ilé, bàbá àgbà yìí ṣe àlàyé ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ wípé, ní ìgbàtí àwọn àjèjì dé, ọ̀dọ̀ Basọ̀run ìgbà náà ni wọ́n lọ tààrà, kí ó tó di wípé Basọ̀run yìí...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Àṣírí Tú O !!! Àwọn Olórí Ìjọba Àtí Agbaàgbà Ilẹ̀ Áfríkà Ni Ìkà, Olè Àti Akótilétà

  Arákùnrin òyìnbó kan tó njẹ Sinato Richards ti tú àṣírí àwọn olórí ìjọba àti àwọn àgbààgbà Áfríkà gégébí ìka, olè àti akótilétà ènìyàn. Nínú ọ̀rọ̀  rẹ̀, ó wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Áfríkà ńsọ kiri lórí ẹ̀rọ ayélujára Tik-tok pé àwọn ará Yúrópù ló ńjí àwọn ohun...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Ó Gbẹnu Tán: Ẹ Wá Wo Bí Wọ́n Ṣe Ń Kó Gbogbo Agbára Sí Ọdọ Ara Wọn Ní Orílè-Èdè Nàìjíríà

  Báwo ni ẹ ṣe fẹ́ kí ìdájọ́ òdodo wà ní orílè-èdè Nàìjíríà, ìjọba mọ́ mí kí ń mọ̀ ọ́ ni wọ́n ń fi ìjọba Nàìjíríà ṣe, a rí àṣírí èyí nínú ìj’ọ́mọ ènìyàn Justice Kayode Olú Ariwoọlá, kété ti wọn ti búra fún un tán gẹ́gẹ́ bíi adájọ́ àgbà ní orílè-èdè Naijiria...
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ NÍ ÌLÚ NIGERIA TI R’ỌRÀN O!

ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ NÍ ÌLÚ NIGERIA TI R’ỌRÀN O!

Ètò ẹ̀kọ́ ní ìlú tí ó fẹ̀gbẹ́ tì wá, èyíinì, Nàìjíríà, ti wá kúkú polúkúrúmuṣu báyi o! Gẹ́gẹ́bí ìròhìn kan tí a gbọ́ ti sọ, ọmọ apá òkè Ọya kan ní ìlú Nàìjíríà, sọ báyi, wípé, “Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ní Nàìjíríà ní wọ́n ti fẹ́ tà, báyi o, fún àwọn oníṣòwò...
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ NÍ ÌLÚ NIGERIA TI R’ỌRÀN O!

A kì í s’òótọ́ inú, kí ọ̀rọ̀ ẹni má d’ayọ̀, b’áyé ẹni bá dojúrú ìwà èèyàn ló yẹ ká wò Òwe Yorùbá Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Wàhálà Dé Fún Àwọn Ajẹgúdújẹrá Ní Naijiria: Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Gbé Ìgbésẹ̀ Lórí Wọn

A ri fọ́nrán kan tí ó’ ṣe àfihàn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì kan ti ńsọ niípa bí àwọn olórí ní Nàìjíríà ṣe ńjí owó ìlú kó lọ sí ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, ó ṣe àpẹẹrẹ Gowon ẹnití ó jí ìdajì owó inú ilé ìfowópamọ́ ìjọba àpapọ̀ tí Naijiria lọ sí ìlù London ní orílẹ-èdè...
Ìyà Tí Ó Njẹ Náìjíríà Kò Ṣ’ẹ̀yìn Àwọn Òyìnbó

Àwọn Yẹ̀yẹ́ Media Sọ̀rọ̀ Tako Akin Fápòhùndà Lórí Ìjọba-Ẹlẹ́kùnjẹkùn

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on X Àwọn tí wọ́n kọ̀, tí wọ́n sọ wípé ọ̀nà ìparun ni àwọn nlọ,...