Aò ní ríbi nílẹ̀ yí, ó d’òkèèrè!

Ọmọ Yorùbá ẹ ṣọ́ra, ìránṣẹ́ ikú, Bill Gates tí wọlé sí ìlú aríremáṣe Nàìjíríà.

Nínú ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí ìránṣẹ́ ikú ọ̀hún, níbi tí ó ti ń ṣe àlàyé fún àwọn ìránṣẹ́ tí yóò ló fún ìgbésẹ̀ yí.

Ṣé aò gbàgbé pé láìpẹ́ yí ni ìránṣẹ́ ikú yí sọ wípé àìsàn Monkey pox lówà níta báyìí, kí àwọn ènìyàn lọ máa gba abẹ́rẹ́ àjẹsára.

Ẹ má lọ o, kódà tí ó bá ṣeé ṣe gan-an, ẹ máa lò óògun òyìnbó kankan mọ.

Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, ìgbésẹ̀ míràn tí ìránṣẹ́ ikú yí tún gbé ní láti ṣe àkóbá fún àwọn aboyún àti ọmọ inú wọn.

Ó ṣe àlàyé bí ìgbésẹ̀ yí yóò ṣe wáyé, ó ní àfikún èròjà àìf’ojúri ti wà nínú ìtọ́jú tí àwọn aboyún yóò máa gbà ní ilé ìwòsàn báyìí, mílíọ̀nù mẹta ni wọn sì ti pèsè láti kó lọ sí ìlú apanilẹ́kún jayé Nàìjíríà, ó wí pé, ìdí ni láti dènà àìsàn ní àkókò ìlóyún àti láti dóòlà ẹ̀mí àwọn ọmọ bíi ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́rin.

Democratic Republic of the Yorùbá latest news updates 04/09/2024

Gbogbo àwa ọmọ Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y), ẹ má jẹ ki a dágunlá lórí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ ikú Bill Gates, lójoojúmọ́ ni kí ẹ jẹ́ kí a máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ọlọ́run Olódùmarè kí ó bá wa pa iná ẹ̀mí rẹ̀, kí o sì sọ ìmọ̀ rẹ̀ di asán lórí àwa I.Y.P.

Gbogbo ìgbésẹ̀ rẹ̀ lórí wa, kí Olódùmarè yíi lé lórí tìran tìran, kí wọ́n má ṣe bọ́ nínú ìnira títí láí. Ṣé ẹ wá rí ẹyin tí ẹ jẹ́ àgbátẹrù àti abẹnugan lórí ìgbésẹ̀ ìránṣẹ́ ikú ní ilẹ̀ Yorùbá, àwọn Ònilẹ̀ Yorùbá ti bínú sí gbogbo yín, ẹ ò tún jẹ́ èèyàn mọ́, ikú tí ẹnikẹ́ni ò kú rí ló máa pa gbogbo yín pátápátá.

Wọn ò dákẹ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò simi lórí èròǹgbà wọn láti dín iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní àgbáyé kù, pàápàá àwa aláwọ̀ dúdú bẹ́ẹ̀ sì ni ojú wọn wà lára àwa ọmọ D.R.Y gidi nítorí wọn mọ irú ìran tí a jẹ́ àti àwọn àlùmọ́ọ́nì tí Olódùmarè fún wa.

Ẹ̀yin aláboyún ní orílẹ̀ èdè D.R.Y, ẹ má lọ gba ìtọ́jú ní ilé ìwòsàn mọ́, kí wọ́n máa bà gbé ohun aburú wọ̀nyí síi yín lára, kí àwọn amúnisìn tó gbé ètò ìwòsàn òfegè wọn de ní àwọn babańlá wa ti ń ṣe ìtọ́jú aboyún tí wọ́n ṣì ń bí wẹ́rẹ́, ẹ jẹ́ kí a padà sí ọ̀nà yí, kí a máa baà bọ́ sínú ìparun.

Nítorí náà, àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, I.Y.P ẹ jẹ́ kí á kíyèsára gidigidi, ẹ má gba abẹ́rẹ́ tàbí lo oògùn òyìnbó, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ máa gbin irúgbìn GMO, ara àwọn irin iṣẹ́ ìránṣẹ́ ikú Bill Gates ni.

Àkókò díẹ̀ lókù fún wa, tí àwọn adelé wa bá ti wọlé sí oríkò ilé iṣẹ́ ìjọba ní àwọn ìpínlẹ̀ méjèèje, kò tún sí ìfòyà mọ́ nítorí pé, ìjọba orílẹ̀ èdè D.R.Y kò ní bá Bill Gates ṣe ohunkóhun papọ̀ láti pa orílẹ̀ èdè wa lára.

A tún fi àkókò yí dúpẹ́ lọ́wọ́ Alágbàkalẹ̀ wa, màmá wá, iya ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla fún akitiyan wọn lórí ìran Yorùbá kí a má báà parun, kí Olódùmarè túbọ̀ máa ṣe àtìlẹ́yìn fún yín màmá.

Ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, kúrò lórí ilẹ̀ wa, ẹ lọ máa tẹ̀síwájú pẹ̀lú ìránṣẹ́ ikú yín ní Nàìjíríà yín lọ́hùn-ún.