Ìròhìn tí a gbọ́ l’orí TikTok, ní yàjóyàjó, ti wá fi hàn wá ní gbangba wálíyà, báyi o, wípé, àfi kí á tètè múra, kí á dá sẹ̀ríà fún ìran ìgbò l’orí ilẹ̀ Yorùbá, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ọjọ́ náà mbọ̀, tí ọmọ Íbò ládugbò á sọ wípé ọmọ Yorùbá kankan kò gbọdọ̀ gba títì àdúgbò kọjá !

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on X

 

Ìjẹgàba Íbò, L'órí Ìran Yorùbá, Ní Ilẹ̀ Yorùbá, Ti Di Ọ̀rọ̀ Àrífín Gbáà

 

Ṣé ní àìpẹ́ yí, ni oríṣiríṣi àwọn ọ̀rọ̀ ti jáde láti ẹnu àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, àti àwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ilẹ̀ Yorùbá, bákannáà, nípa oríṣiríṣi ìwà àti ìṣesí ìjẹgàba àwọn ọmọ Íbò, lórí ọmọ Yorùbá, ní ilẹ̀ Yorùbá, ṣùgbọ́n pabambarì tí a tún gbọ́, nínú ìròhìn tí a tún rí lórí TikTok yí ni wípé, ní agbègbè Ẹgbẹ́dá, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, nṣe ni aṣiwèrè aláìlẹ́kọ ọmọ Íbò kan, kọ’lẹ́ tó miringindi síbẹ̀ o, tí ó sì ṣe ẹ̀ṣọ́ tí ó dáradára gbogbo lóríṣiríṣi sínú àti sí ara ilé yí; ṣùgbọ́n tí ó wá gbé ìkéde síta o, wípé, ayálégbé (tenant) tí òun máa gbà láàyè láti jóko, ìyẹn ni láti yá ilé náà gbé, níláti jẹ́ ọmọ Íbò !

Tí kò bá wá jẹ́ Ọmọ Íbò o, wípé òun lè gba ọmọ ìpínlẹ̀ Ẹdo tàbí ìpínlẹ̀ Delta (èyí tí wọ́n wà nínú nàìjíríà ní tiwọn). Ọmọ Íbò, onílé yí, tí ó sì jẹ́ ọmọ Nàìjíríà, gẹ́gẹ́bí a ṣe mọ̀, tún wá sọ síwájú síi o, wípé, tí òun kò bá wá rí ọmọ Íbò tí ó máa gba ilé náà, tí òun ò sì tún ri ọmọ Ẹ̀dó tàbí ọmọ Delta, wípé òun wá le gbé ilé náà fún ẹnikẹ́ni o, láti ìran k’íran tí ìbáà wù kó jẹ́, tàbí ẹ̀yàkẹ́yà tí ìbáà wù kójẹ́, láti máa gbé inú ilé náà; ṣùgbọ́n, tòun ṣáà ni wípé, òun ò fẹ́ ọmọ Yorùbá kankan, láyé, ní sàkání ilé òun, ìlé tí ó wà ní Ẹgbẹ́dá, ní ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá!

Ìjẹgàba Íbò, L'órí Ìran Yorùbá, Ní Ilẹ̀ Yorùbá, Ti Di Ọ̀rọ̀ Àrífín Gbáà

Njẹ́, tí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá kan bá sọ wípé, nṣe ni kí á lé gbogbo ìran Íbò kúrò ní Ilẹ̀ Yorùbá, pátápátá, ní kété tí ìjọba wa bá ti wọlé sínú oríkò ilé-iṣẹ́ Ìjọba (Secretariat), njẹ́ a lè sọ wípé ohun tí wọ́n sọ, wípé ó kọjá ẹnu wọn bí?

Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọmọ Yorùbá ni ó jẹ́ wípé, bóyá, ọ̀rọ̀ yí kòì tíì yé wọn, dáradára, wípé, ìkórira àti ẹ̀gàn tí àwọn Ìran Íbò, tí wọ́n ní sí ìràn Yorùbá, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ kọjá èyí tí ìran Fúlàní ní sí ìran Yorùbá pàápàá.

Tí orílẹ̀-èdè Yorùbá bá lé gbogbo ọmọ Íbò kúrò lórí ilẹ̀ Yorùbá, tí wọn kò sì gba kọ́bọ̀ lórí dúkìá-kí-dúkìá tí kò ṣeé gbé lọ, nígbàtí a bá lé wọn lọ tán, kúrò lórí ilẹ̀ wa, ó tó bẹ́ẹ̀, ó ju bẹ́ẹ̀ lọ.

Ẹ̀bi wọ́n kọ́ọ, nígbàtí ó jẹ́ wípé ọmọ Yorùbá náà, ni ó máa máa ta ilẹ̀ Yorùbá fún Íbò, wọn ò ṣe ní máa hùwà ẹranko àti aláìlọ́pọlọ tí a mọ̀ wọ́n sí?

Àmọ́ ṣá o! – ó ti wá hàn gbangba báyí wípé, kò sí ojú àánú wèrè kankan o, fún ẹnikẹ́ni, ìran-kí’ran, tí kò bá bọ̀wọ̀ fún ọmọ Yorùbá, ní kété tí ìjọba wa, lábẹ́ àkóso Olórí Adelé, Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọrẹ́, báti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ nínú Secretariat gan-gan-gan.

Wọ́n ti nṣiṣẹ́ lọ, nísiìyí, a dẹ̀ máa rẹ́yin àwọn agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, àwọn olè àti ọlọ́ṣà tí ó jẹ gàba, ní àkókò yí, lórí ilẹ̀ wa; a máa rẹ́yìn wọn, pátápátá, ní àìpẹ́ àti ní àìjìnà yí, nígbà náa ni ohun gbogbo á wá bẹ̀rẹ̀ sí rí bí a ṣe fẹ́ kó rí gan-gan.

say no to gmo foods, seed, crop. yoruba warns african

Ká Ìròyìn Síwájú sí:

Èdùmàrè yíò máa tọ́ wa sọ́nà, ohun gbogbo tí a máa ṣe, tí ọmọ Yorùbá, ní orí-ilẹ̀ Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, yíò fi ní ìsimi, pátápátá, kúrò lọ́wọ́ àwọn agbéraga ọmọ Íbò. Kí ẹnikẹ́ni ó má ṣe rò wípé ọmọ Íbò kan wà, tí ó ro Ire kankan sí ọmọ Yorùbá, lórí ilẹ̀ Yorùbá, o!

Ṣùgbọ́n, ohun tí ó bá gbà, pátápátá ni a máa fun; ìran Íbò kankan, láyé, kò lè gba ilẹ̀ Yorùbá, tàbí fi ìwọ̀sí lọ ọmọ Yorùbá, kankan, láyé, mọ́!

Ègbé sì ni fún ọmọ Yorùbá náà, tí ó máa fi ojú àánú wo ọmọ Íbò, nígbàtí ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí njẹ wọ́n. Ó tó gẹ́ẹ́. Kò ní dáa fún ìyáláya ọmọ Íbò lórí ilẹ̀ Yorùbá. Èyí kìí ṣe ìkóríra; tàbí ìkà; rárá o! Ọ̀rọ̀ ìran ni a nsọ!