A ríkà nínú ìwé ìròyìn kan tí ó jáde ní ọjọ́ àìkú, oṣù keje ẹgbàá ọdún ó-lé-mérìn-lé-lógún, wípé, arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ‘Femi ni ìlú Oshogbo, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ro gbogbo bí nǹkan ṣe le koko tí ohun gbogbo di ìnira la ìlú já, tí ohun gbogbo ko rọrùn fún un mọ́ ní àkókò ìjọba Tinubu gẹ́gẹ́bí a ṣe gbọ́ pé arákùnrin náà ń s’àròyé fún àwọn alájọgbé rẹ̀ kí ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá yìí tó ṣẹlẹ̀.

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on X
Ìbẹ̀rùbojo Gba Ìlú Oshogbo Kan Lórí Bí Ọkùnrin Kan Ṣe Bẹ́ Sínú Odò

A ríkà nínú ìwé ìròyìn kan tí ó jáde ní ọjọ́ àìkú, oṣù keje ẹgbàá ọdún ó-lé-mérìn-lé-lógún, wípé, arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ‘Femi ni ìlú Oshogbo, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ro gbogbo bí nǹkan ṣe le koko tí ohun gbogbo di ìnira la ìlú já, tí ohun gbogbo ko rọrùn fún un mọ́ ní àkókò ìjọba Tinubu gẹ́gẹ́bí a ṣe gbọ́ pé arákùnrin náà ń s’àròyé fún àwọn alájọgbé rẹ̀ kí ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá yìí tó ṣẹlẹ̀.

Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, World

Ṣebí irú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí kì ‘bà ma tọ́ sí ẹnikẹ́ni lórí ilẹ̀ DRY mọ́, ká wípé láti ìgbà tí a ti gbé ìjọba Olómìnira wa ka’lẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún yí ní àwọn agbésùnmọ̀mí tí ìlú Nàìjíríà, tí wọ́n jókòó lórí ilẹ̀ wa bá ti kúrò ní, ètò ìgbáyé gbádùn àwa ọmọ DRY kò bá ti bẹ̀rẹ̀, ohun burúkú gbogbo tí ó ń ṣẹlẹ̀ wọ̀nyí kò kàn wọ́n, àwọn aláìní ojútì, tí ìrìn ẹsẹ̀ wọn kò sì yípadà, wọ́n tún tí fi ẹ̀mí IYP míràn ṣ’òfò sí’nú odò Gbodofon nílùú Oṣogbo o, kí Olódùmarè gbà wá lọ́wọ́ àwọn ajá àwọn òyìnbó ooo.

Ká Ìròyìn Síwájú sí: