Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́

Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́

Awọn bàbá wa sọ wípé, Ọmọdé gbọ́n, Àgbà gbọ́n, laafi dá’lẹ̀ Ifẹ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sọ wípé, Ọwọ́ ọmọdé kò tó Pẹpẹ; ṣùgbọ́n, àgbàlagbà tí ọwọ́ rẹ̀ tó pẹpẹ nkọ́? ti ó bá gbé kèrègbè l’ati orí pẹpẹ, à ti mú nkan t’ó wà nínú kèrègbè náà nkọ́? Ọwọ́...
Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́

Orúkọ Àmútọ̀runwá Nílẹ̀ Yorùbá

Yorùbá bọ̀, wọ́n ní “Orúkọ ọmọ ni ìjá’nu ọmọ.” Òwe Yorùbá Oríṣiríṣi orúkọ l’ó wà ní ilẹ̀ Yorùbá. Àwọn Yorùbá kìí dédé fún ọmọ l’orúkọ láì ní ìdí pàtàkì. Ìdí ni’yí tí wọ́n fi np’òwe wípé “Ilé l’a nwò, kí á tó s’ọmọ l’orúkọ.” Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira...
Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́

Yoruba Society: The People & the Culture

Yoruba, as an indigenous ethnicity, dwelling upon their own ancestral land, have existed from time immemorial. Yoruba society is one in which the mantra of “Omolúàbí” reigns supreme. It is the distinguishing factor of the Yoruba person and his society....