Èléyí  fihàn dájú dájú wípé oúnjẹ GMO ti wà kákiri nínú ọjà D.R.Y. báyi.

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on X

O jẹ́ oun tí ó ba ènìyàn nínú jẹ́ lọ́pọ̀lọ́pọ̀. Ti kò bá ṣe wípé, àwọn Jàndùkú, aláyé bàjẹ́ Gómìnà Nigeria Agbésùnmọ̀mí, ti wọ́n takú sí Sekiteriati àwa ọmọ I.Y.P. ni, àwọn Adelé ilẹ̀ Yorùbá kò bá ti mójú tó gbogbo ounjíjẹ tí àwọn ọmọ aládé, I.Y.P, njẹ ní àsìkò yí..

Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, World

Ká Ìròyìn Síwájú sí:

 

say no to gmo foods, seed, crop. yoruba warns african