Àbí ẹ̀ ò rí nǹkan bí, ẹ wo ọ̀dọ́ Ààrẹ Bassirou Fàyè ti òrílẹ̀ èdè Senegal tí ó ń fẹ́ ire fáwọn èèyàn rẹ̀, nígbà tí ìkà ti Naijiria, ni’bi tí a ti  jáde báyìí ń wá ìnira fún àwọn ìran tirẹ̀, ìyẹn tó bá jẹ́ pé ìran Yorùbá ló jẹ́ ní tòótọ́ bí ó ṣe ń pe ara rẹ̀ o.

Ààrẹ Senegal Mú Owó Ìrìnnà Kúrò Ní Àwọn Onjẹ Tí Ó Nwọlé Sí Ìlú Rẹ̀ - Democratice republic of the Yorùbá

Ṣé ẹ rí ìdí tí ẹ má fi mọ̀ pé inú ìgbádùn ni àwa omo IYP (ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá) wà.

Àti ìdí tí àwa ojúlówó ọmọ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ṣe ní ìrètí ògo ọjọ́ ọ̀la tí ó fi ọkàn balẹ̀ làti owó àwọn odò wá lórí ilẹ̀ DRY, ilè Olómìnira wa, àwọn odo wá lè ṣe, wón má ṣeé , gbogbo wa là má jèrè ilẹ̀ Democratic Republic of the Yorùbá ní agbára Olódùmarè. Ire o.

Ka Ìròyìn:Ohun Nlá Ṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Yorùbá Ní Ọjọ́ Kéjìlá, Oṣù Kẹ́rin, Ọdún 2024!

Ààrẹ Senegal Mú Owó Ìrìnnà Kúrò Ní Àwọn Onjẹ Tí Ó Nwọlé Sí Ìlú Rẹ̀ - Democratice republic of the Yorùbá

Ka Ìròyìn: Bill Gates: Ìránṣẹ́ Apànìyàn Tí Àṣìtáánì Nlo Lati Ṣe’Jàǹbá Fun Aláwọ̀dúdú